Matthew 20:1

Òwe àwọn òṣìṣẹ́ nínú ọgbà àjàrà

1 a “Nítorí ìjọba ọ̀run dàbí ọkùnrin tí ó jẹ́ baálé kan, tí ó jíjáde lọ ní kùtùkùtù òwúrọ̀, tí ó gba àwọn alágbàṣe sínú ọgbà àjàrà rẹ̀.
Copyright information for YorBMYO